Lyrics Bá’núsọ Brymo

Abéré á lo Abéré á lo K’ó nà okùn ó tó dí ò

A ò ní dé bá won A ò ní dé bá won Ení bá ní a máà de ò Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Omijé á gbe Omijé á gbe Ìbànújé á dèrin ò Eniafé Eniafé lamò o A ò mo’ni tó fé ni ò Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Ení bá ma b’ésù jeun Síbíi rè á gùn gan Eni ò mò áù Ówá jeé Òsèlú mà ló layé ò Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Èyin ará Ewá gbó òò Òrò kan se ùrùn ùrùn nínú iii Sé kín só Kín só Ká bá’núso Bá’núso N’òní b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here